Ojúṣe wa ni láti ṣe ètò ìgbéga àti ìdàgbàsókè àṣà, ìṣe àti ìṣẹ̀m̀báyé Yorùbá kí àwọn ọmọ tí a bá bí lọ́la lè máa fi àṣà wa yangàn, kí wọ́n sì máa gbé e lárugẹ ní gbogbo àgbáyé. Àṣà Yorùbá kò ní parun ò. Àṣẹ
Yoruba Cultural Heritage Knowledge and Development Initiative
Yoruba Cultural Heritage Knowledge and Development Initiative is registered with the Corporate Affairs commission to keep up the high spirit of promoting Yoruba cultural heritage and a renaissance of values, ethics and norms